Indigene Study Database

The result below are the list of added genomics-related words in different languages and their English translations

Browse Languages


Showing results for "Yoruba - English" Translations

Yoruba Neologism English Translation Category
Àbíkú No Death (at infancy) due to sickle cell condition, etc W
Dìndìrin No Mental retardation or imbecile which could be hereditary W
Àbísínwín No Puerperal psychosis which some Yoruba believe is hereditary W
Àdámọ́ No A Yoruba word for inherited, inborn, innate, or natural traits W
Àfise/iṣé ayé No Metaphysical act which is non-hereditary W
Yoruba gbagbo ninu àrùn àjogúnbá bi: Arunmọléègun, Ìtọ ṣúgà, Ẹ̀jẹ̀ ríru, Ikọ́ gbọfungbọfun, Àbísínwín, Àwọ́ká, Ikọ́ fee, Ori túùlu, Wárápá, Ifo, Àrùn ọpọlọ/wèérè/aganna ati bẹ̀bẹ̀ lọ́. No Yoruba believe in transmissibility or heritability of illness like: Bone-crushing disease of children (Sickle cell disease), Diabetes mellitus, High blood pressure, Tuberculosis, Puerperal psychosis, Rheumatism, Asthma, Migraine, Epilepsy, Eczema, Mental illness and so on. W
Yoruba gbagbo ninu ise tabi iwa àjogúnbá bi: Àwọ, Ilà ọwọ́, Ìlù lílù, Ọ̀rọ̀ sísọ, Ìbínú/inú bíbí, agídí, Ìkó ni mọ́ra, Ìkanra, ajangila, suurù, Ìwàpẹ̀lẹ́, ìwà tútù, oti-amupara ati bẹ̀bẹ̀ lọ. No Yoruba believe in transmissibility or heritability of character and behavioral traits like: complexion, skin type, skin color, lines on the palm, palm creases, prowess in playing drums, talkativeness or oratory prowess, (excessive) anger, stubbornness, hospitability, hostility/touchy, bullying, gentleness, gentility, patience, alcoholism and so on. W
Eelá No A genetically-transmitted skin disease W
Ẹ̀jẹ̀/ Ẹ̀jẹ̀ pupa No Blood W
Ẹ̀jẹ̀ ìran No Blood (genetic trait) that runs in a family lineage W
Erejú No Parent’s physical appearance that may be inherited by a child W
Ẹyin No Female gamete W
Fòníkú fò̩ladìde No An heritable condition where the victim falls sick repeatedly in a short time frame W
Ọ̀bẹ asìlò No A bastard (who does not manifest expected and known family traits) W
Ọdẹ orí/ọlọ́dẹ orí No Mental illness or psychiatry disorder; a mentally ill person; madness which Yoruba believe could be heritable W
Ògún òru No An illness that causes the sufferer to fall unconsciously at midnight to the ground and be stiff for minutes W
Okùn ẹbí No Gene W
Oríkì ìdílé No Family eulogy or panegyric which often highlights their peculiar traits W
Ẹ̀jẹ̀ funfun No Male and female gamete C
Ẹ̀jẹ̀ kan le mú ju ìkejì lọ/ Ẹ̀jẹ̀ kan ma nmú ju ìkan lọ No Some gene could be dominant over the other in the context of transmissibility of heritable traits C
Ẹ̀jẹ̀ ma nràn No Blood is heritable C
Ẹ̀jẹ̀ mímú No Dominant trait C
Kì ràn No Any behavioral trait which is not heritable C
Omi ara No Male and female sex gametes released during coitus C
Súúrà àwọ̀ No Character or phenotypic resemblance C
Tí ẹ̀jẹ̀ bàbá àti ìyá bárí bákan na, fòníkú fọ̀ladìde l’àwọn ọmọ yóò jẹ No If both parents have the same genotype (SS), their children will have sickle cell disease C
A n fi àwọ̀ jo̩ ìran ẹni No A person’s skin traits or complexion is heritable from his family gene A
Baba rẹ loo jọ No The child resembles his father A
Ẹ má ba wí, àti ilé ló ti gbe wá No Don’t scold the child; it’s an inherited trait! A
Ẹ̀ku diran ọ̀jẹ̀, iṣe baba rẹ ni i ṣe No The character traits that a child exhibits are inherited from his father (and such are known with their ancestors) A
Ẹni o bini la n jọ No A child will resemble the person who gave birth to him A
Imí ò jọ ẹni tó ṣu ú No A child (behavior) does not resemble his parents A
Inú ẹ̀jẹ̀ ìbí l’ówà No Trait is innate in the blood A
Irú ìró ni ìborùn, irú bàbá l’ọmọ No Like father like son; a Yoruba saying for resemblance A
Ìwá dà bí àdámọ́ fún gbogbo ènìyàn, kò sí adára má kù sí ibì kan No Character is inborn/innate; there is no one without some behavioral flaws A
Kálukú ló n hu ìwà tí ẹ̀ No Every individual inherently behaves in a distinct way A
Kí mánigbàgbé má ba parun nínú ìdílé yẹn No For the essence of transmissibility and preservation of traits in the family A
Kí tán lára wèèrè, kó má ku páì No Even if a mad person is rehabilitated, he will still erratically manifest some insanity A
Kò jọ ìyá, kò jọ baba, àdíjà lẹ̀ ọmọ ni No A child who does not resemble either of his parents; a bastard, brings controversy A
Mo kòó, á ma ní àpèjúwe No Every individual has some descriptive traits or characteristics A
Níboní wọ́n tigbe ọmọ èyí wá No The progenitor of a child is questionable because of the presence or absence of peculiar family character or traits A
Oniran ni iran njọ No Generational trait is reflected in resemblance A
Okùn ẹbí yi ju èyí tí a fin di igi lọ No Family gene bonds very strongly A
Ọmọ bọ́lá nlé ni No A child inherited family wealth, traits, etc A
Ọmọ ẹni ò bá jọni à bá yọ No The joy of every parent is having their offspring resemble them A
Ọmọ erín jogún ọlá No A child has inherited the parent’s or family’s prestige, attributes or traits A
Ọmọ já ìfun ìyá tabi bàbá rẹ̀ jẹ No A child takes after his mother or father in character or behavior A
Ọmọ jọ bàbá rẹ̀ bí ìmumu / Ó jọ bàbá rẹ̀ bí ìmumu No The child is a replica of his father A
Wọ́n bí ọ ni ìsọ̀ àgùntàn, o ya ìsọ̀ màálu No An expression to describing a child that behaves or acts at variance to the parents’ character A
Aàtọ̀ eré l’afi bí ẹsin/ Eré sísá l’afi bí ẹsin No Horses inherit the ability to race, meaning a family’s traits are heritable P
B’ọ́mo ò jọ ṣòkòtò, yi o jo kíjìpá, ẹní ó bí ni l’ájọ No A child must display some of the characters or traits of his parents; if a child does not resemble the father, he should resemble the mother P
Irún kún aṣọ́ ya, èròjà wèèrè ti pé No Unkempt appearance is a sign of insanity: this underscores Yoruba belief in resemblance P
Ọkùnrin tí kò bá ní aàrun kankan l’ára kòle bímọ No A figurative expression which means that inherited trait is inevitable P
Ọmọ àjànàkú kan kiì ya àrá, ọmọ tí ẹyá bá bí ẹyá ní njọ No A proverb which means that a child must necessarily resemble his parents P
Ọmọ kìí bá ìpele ìyá rẹ̀, kí ó si aṣọ mú No A child will always take after his mother’s traits P
Òwú ti ìyá gbọ̀n, l’ọmọ o rán No A child must exhibit his inherited mother’s behavior P
Ọmọ t’ẹ́kun bí, ẹkùn ni ó jọ; òtòlò òní yà j’ọ̀rá No A child must resemble his parents – only a bastard differs P
Wo ẹnu ilẹ̀, wo ẹnu ọkọ́ No An idiomatic expression that a child resembles his parents well P
Wọ́n bí ọ b’ójú, o mọ ìran wò No A way of describing a child that is not behaving like his parents P
Yoruba Neologism English Translation Category

Submit genomics-related words

You can submit genomics-related words in your indigenous language with their English equivalents on this website. Please note that submitted words will be reviewed by the Site Administrator before they can appear public on this site. To submit such words, click the link below

Login/Signup to add new word

Suggestion

Contact admin, if the language you intend to translate is not available.